Oritse Femi Ft Portable – Oro Aje
Music

Oritse Femi ft Portable – Oro Aje

Oritse Femi ft Portable – Oro Aje

Oritse Femi ft Portable – Oro Aje

Renowned Nigerian recording artiste, Oritse Femi unites with raving Nigerian act, Portable to unlock a jam tagged; “Oro Aje”. Below is the lyrics to the song to enable you sing along.

Awon kan ma lowo awon kan oni le lowo
Owun a ni lan naniAje mi ni owo mi ni ko kanyin
Kokan aye
Bi mo sehun pa owo mi
Sebi emi mo mo mi
Te ba le shoro aje, tori oro aje
oro aje iyen lo sure

Ika oburu eniyan lo gbero ika
Eda aye le,Ori eni lo gbeni ga
Iya o ye ori ayo loye eniyan
ki emi sa ma pa owo mi
kin ma se aye dede
Temini kowo ti pe,kin de wa,
bi to gbayi loo
Maje aye ori ma tun se ore fun
awon eyan kan
Awon kan ma gbe enu si ko le gba,
tiwon ma lo…Ahaaha ti ba ti gba owo mi
mo ma sa ye dede

Baba mo roowo re ninu aye mi,
aye mi dara o mo wa sope
Eleda mi gbe mi de po ade mi,
Ori Aje mi ma se je ko bo oo
Ahhhh….se bi ola mi ni Aje mi ni ko kan yin
Won se bolatan o Ola ku seyin Opooor gan
Te ba le shoro aje,tori oro aje oro aje
eyen lo sure

Ika oburu eniyan lo gbero ika
Eda aye le,Ori eni lo gbeni ga
Iya o ye mi ayo lo ye eniyan
ki emi sa ma se aye dede
Temini kowo ti pe,kin de wa bi
to gbayi lo
Maje aye ori mi ma tun se ore fun
Awon eyan kan,
Awon kan ma gbe enu si ko le gba
ti won ma lo…Ahaaha ti ba ti pa owo mi mo ma sa ye dede
Aloyin lowun ree o..
mo ni ko ma lo ri mi tan,
ni mo se sa pa moo,

Ma pe mi kin wa lo ja
Owo ni ko pe mi kin wa lo gba
Omo oro mi wuwa ika
Omo oro mi sapa mo oo
ko ma lo ri etan o is better thatn see finish oo …..
Zazu Zeh o!!
Emi ni werey olorin
Idamu adugbo yin idamu adugbo yin
Wahala musician,African mafian
Awuuu mmm awon omo Naija awo lo
ma se yahoo tori ko sowo
Ika oburu eniyan lo gbero ika

Eda aye le,Ori eni lo gbeni ga
Iya o ye ori ayo loye eniyan
ki emi sa ma pa owo mi
kin ma se aye dede
Temini kowo ti pe,kin de wa bi
to gbayi loo,
Maje aye ori mi ma tun se ore fun
Awon eyan kan,
Awon kan ma gbe enu si ko le gba
ti won ma lo…Ahaaha ti ba ti gba owo mi mo ma sa ye dede
Ma pe mi kin wa lo ja
Owo ni ko pe mi kin wa lo gba oo
Mmmm ma je ko rip ee
ko to ri ee oo omo oro mi sa loo

0 0 votes
Article Rating
Subscribe
Notify of
guest
0 Comments
Inline Feedbacks
View all comments

0
Would love your thoughts, please comment.x
()
x